Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Àwọn ọmọ ogun wí:“Wò ó, èmi dán wọn wo; nítorí pékí ni èmi tún le è ṣe? Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ènìyàn mi?

Ka pipe ipin Jeremáyà 9

Wo Jeremáyà 9:7 ni o tọ