Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 9:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísínsìnyìí, ẹ̀yin obìnrin ẹ gbọ́ọ̀rọ̀ Olúwa. Sí etí yín síọ̀rọ̀ ẹnu rẹ. Kọ́ àwọn ọmọbìnrinyín ní ìpohùnréréẹkún, kí ẹ sì kọ́ ara yín ní arò.

Ka pipe ipin Jeremáyà 9

Wo Jeremáyà 9:20 ni o tọ