Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì wí pé, nítorí pé wọ́n ti kọ òfin mi sílẹ̀, èyí tí mo gbé kalẹ̀ níwájú wọn, wọn ṣe àìgbọ́ràn sí wọn, wọn kò sì rìn nínú òfin mi.

Ka pipe ipin Jeremáyà 9

Wo Jeremáyà 9:13 ni o tọ