Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi yóò sì sọ Jérúsálẹ́mù di òkìtìàlàpà àti ìhò àwọn ìkokò.Èmi ó sì sọ ìlú Júdà di ahorotí ẹníkẹ́ní kò sì ní le è gbé.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 9

Wo Jeremáyà 9:11 ni o tọ