Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kódà, ẹyẹ àkọ̀ ojú ọ̀run mọ ìgbàtirẹ̀, àdàbà, alápáǹdẹ̀dẹ̀ àti lékèélékèémọ àkókò ìsípòpadà wọn. Ṣùgbọ́n àwọnènìyàn mi kò mọ ohun tí Ọlọ́run wọn fẹ́.

Ka pipe ipin Jeremáyà 8

Wo Jeremáyà 8:7 ni o tọ