Jeremáyà 8:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
“È é ṣe tí a fi jòkó ní ibí yìí?A kó ara wa jọ!Jẹ́ kí a sá lọ sí ìlú olódi kí o sì ṣègbé síbẹ̀.Nítorí tí Olúwa Ọlọ́run wa tipinnu pé a ó ṣègbé. Yóò sì fúnwa ní omi onímájèlé láti mu, nítorí àwa ti sẹ̀ sí i.