Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 8:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ wọ́n tijú fún ìṣe ìríra wọn? Bẹ́ẹ̀ kọ́,wọn kò ní ìtìjú rárá; wọn kò tilẹ̀ mọbí wọ́n ti ṣe ń mí oru-ìtìjú. Nítorí náàwọn yóò ṣubú pẹ̀lú àwọn tó ti ṣubú,a ó sì fà wọ́n lulẹ̀ nígbà tí a bá ń fiìyà jẹ wọ́n,ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 8

Wo Jeremáyà 8:12 ni o tọ