Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ní ìgbà náà ni Olúwa wí pé, wọn yóò mú egungun àwọn ọba Júdà àti egungun àwọn ijoye, egungun àwọn àlùfáà àti egungun àwọn wòlíì àti egungun àwọn olùgbé Jérúsálẹ́mù kúrò nínú ibojì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 8

Wo Jeremáyà 8:1 ni o tọ