Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 7:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ẹ̀yin yóò ha jalè, kí ẹ pànìyàn, kí ẹ se pánṣágà, kí ẹ búra èké, kí ẹ sun tùràrí sí Báálì, kí ẹ sì tọ Ọlọ́run mìíràn tí ẹ̀yin kò mọ̀ lọ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 7

Wo Jeremáyà 7:9 ni o tọ