Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 7:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa Àwọn ọmọ ogun wí: Èmi yóò tú ìbínú àti ìrunú mi sí orílẹ̀ yìí ènìyàn àti ẹranko, igi, pápá àti èṣo orí ilẹ̀, yóò sì jó tí kò ní ṣe é pa.

Ka pipe ipin Jeremáyà 7

Wo Jeremáyà 7:20 ni o tọ