Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Àwọn ọmọ ogun wí:“Ẹ ké àwọn igi náà lulẹ̀kí ẹ sì mọ odi ààbò yí Jérúsálẹ́mù ká.A gbọdọ̀ fi ìyà jẹ orílẹ̀ èdè yìínítorí pé ó kún fún ìrẹ́nijẹ.