Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 6:28-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. Ọlọ́tẹ̀ tí ọkàn rẹ̀ le ní gbogbo wọn. Wọ́n ńlọ káàkiri láti sọ̀rọ̀ òdì. Wọ́n jẹ́ idẹ àti irin,wọ́n sì kún fún ìwà ìbàjẹ́.

29. Ewìrì a fẹ́ná kíkankíkán,kí ó lè yọ́ òjé,ẹni tí ń yọ́ ọ ń yọ́ ọ lásán;a ko si ya ènìyàn búburú kúrò.

30. A pè wọ́n ní fàdákà tí a kọ̀ sílẹ̀,nítorí Olúwa ti kọ̀ wọ́n sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 6