Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 50:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé èmi yóò ru,bẹ́ẹ̀ ni èmi yóò gbé sókè sí Bábílónì àwọn orílẹ̀ èdèńlá láti ilẹ̀ àríwá. Wọn yóò gba àyà wọn lẹ́gbẹ́ rẹ̀;Láti àríwá wá, à ó sì mú ọ. Ọfà wọn yóòdàbí ọfà àwọn akọni alákíkanjú tí wọn kì í wà lọ́wọ́ òfo

Ka pipe ipin Jeremáyà 50

Wo Jeremáyà 50:9 ni o tọ