Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 50:45-46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

45. Nítorí náà, gbọ́ ohun tí Olúwa sọ nípa Bábílónìẹni tí ó gbìmọ̀ lòdìsí Bábílónì; n ó sì paagbo ẹran wọn run.

46. Ní dídún fèrè Bábílónìgbogbo ilẹ̀ ayé yóò mì tìtìigbe rẹ̀ yóò sì búja gbogboàwọn orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Jeremáyà 50