Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 50:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ sọ ọ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ sì kéde,kí ẹ sì gbé àṣíà sókè.Ẹ kede, ẹ má sì ṣe bòó wí pé,‘a kó Bábílónì,ojú tí Bélì,a fọ́ Merodákì túútúú,ojú ti àwọn ère rẹ̀,a fọ́ àwọn òrìṣà rẹ̀ túútúú.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 50

Wo Jeremáyà 50:2 ni o tọ