Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 50:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“A ti fọ́n Ísírẹ́lì ká, Kìnnìún sì ti lé e lọ.Ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ jẹ ẹ́ ni Ọba Ásíríà,ẹni tí ó sì jẹ eegun rẹ̀kẹ́yìn ni Nebukadinésárì Ọba Bábílónì.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 50

Wo Jeremáyà 50:17 ni o tọ