Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 50:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kígbe mọ-ọn ní gbogbo ọ̀nà!Ó tẹríba, òpó rẹ̀ sì yẹ̀,níwọ̀n ìgbà tí ó ti jẹ́ wí pé èyí ni ìgbẹ̀san Olúwa,gbẹ̀san lára rẹ̀.Ṣe síi gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe sí àwọn ẹlòmìíràn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 50

Wo Jeremáyà 50:15 ni o tọ