Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 5:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò ha yẹ kí ẹ bẹ̀rù mi?” ni Olúwa wí.“Kò ha yẹ kí èyin ó wárìrì níwájú mi bí?Mo fi yanrìn pààlà òkun,èyí tí kò le è rékọjá rẹ̀ láéláé.Ìjì lè jà, kò le è borí rẹ̀;wọ́n le è bú, wọn kò le è rékọjá rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 5

Wo Jeremáyà 5:22 ni o tọ