Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 5:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé, nígbà tí àwọn ènìyàn bá sì béèrè wí pé, ‘Kí ni ìdí rẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run wa fi ṣe gbogbo èyí sí wa?’ Ìwọ yóò sì sọ fún wọn wí pé, ‘Ẹ̀yin ti kọ̀mí sílẹ̀, ẹ sì ń sin Ọlọ́run àjèjì ní ilẹ̀ yín. Nísinsìnyìí, ẹ̀yin yóò máa sin àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe ti yín.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 5

Wo Jeremáyà 5:19 ni o tọ