Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 5:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Ọlọ́run alágbára wí:“Nítorí tí àwọn ènìyàn ti sọ àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí;Èmi yóò sọ ọ̀rọ̀ mi lẹ́nu wọn di iná,àti àwọn ènìyàn wọ̀nyí di igi tí yóò jórun.

Ka pipe ipin Jeremáyà 5

Wo Jeremáyà 5:14 ni o tọ