Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 49:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa Kédárì àti ìjọba Ásọ́rì èyí ti Nebukadinésárì Ọba Bábílónì dojú ìjà kọ:Èyí ni ohun tí Olúwa sọ:“Dìde kí o sì dojú ìjà kọ kédárì,kí o sì pa àwọn ènìyàn ìlà oòrùn run.

Ka pipe ipin Jeremáyà 49

Wo Jeremáyà 49:28 ni o tọ