Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 49:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa Dámásíkù:“Inú Hámátì àti Árípádì bàjẹ́ nítorí wọ́n gbọ́ ìròyìn búburú, ìjayà dé bá wọn,wọ́n sì dààmú bí omi òkun.

Ka pipe ipin Jeremáyà 49

Wo Jeremáyà 49:23 ni o tọ