Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 49:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí kìnnìún ti ń bọ̀ láti igbóJódánì wá sí pápá oko ọlọ́rà áèmi yóò lé Édómù láti ibi ilẹ̀ rẹ̀ ní kíákíá.Ta ni ẹni náà tí èmi yóò yàn fún èyí?Ta lo dàbí èmi, ta ni ó le pè mí níjà?Ta ni olùsọ́ àgùntàn náà tí ó lè dúró níwájú mi?”

Ka pipe ipin Jeremáyà 49

Wo Jeremáyà 49:19 ni o tọ