Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 49:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìpayà tí ìwọ ti fà sínúìgbéraga ọkàn rẹ sì ti tàn ọ́ jẹ;ìwọ tí ń gbé ní pàlàpáláàpáta tí o jòkó lórí ìtẹ́ gígasíbẹ̀ o kọ́ ìtẹ́ rẹ ga gẹ́gẹ́ bí ẹyẹ idì;láti ibẹ̀ ni èmi yóò ti mú ọ sọ̀kalẹ̀ wá,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 49

Wo Jeremáyà 49:16 ni o tọ