Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 49:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa wí bí ẹnikẹ́ni tí kò bá yẹ kí ó mu ife náà bá mú un, kí ló dé tí ìwọ yóò fi lọ láìjìyà? Ìwọ kò ní lọ láìjìyà; ṣùgbọ́n ìwọ yóò mu un.

Ka pipe ipin Jeremáyà 49

Wo Jeremáyà 49:12 ni o tọ