Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 49:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ti Ámónì:Ohun tí Olúwa sọ nìyìí:“Ísírẹ́lì kò ha ní ọmọkùnrin?Ṣé kò ha ní àrólé bí?Kí ló wá dé tí Mákómù fi jogún Gádì?Kí ló dé tí àwọn ènìyàn rẹ̀ ń gbé ìlú rẹ̀?

Ka pipe ipin Jeremáyà 49

Wo Jeremáyà 49:1 ni o tọ