Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 48:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Móábù ti wà ní ìsinmi láti ìgbà èwe rẹ̀ wábí i ọtí wáìnì lórí gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ̀ rẹ̀,tí a kò dà láti ìgò kan sí èkejìkò tí ì lọ sí ilẹ̀ ìgbèkùn rí.Ó dùn lẹ́nu bí ó ti yẹ,òórùn rẹ̀ kò yí padà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 48

Wo Jeremáyà 48:11 ni o tọ