Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 46:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ni nǹkan tí mo tún rí?Wọ́n bẹ̀rù,wọ́n sì ń padà sẹ́yìn,wọ́n ti ṣẹ́gun àwọn jagunjagun.Wọ́n sá,wọn kò sì bojú wẹ̀yìn,ìbẹ̀rù sì wà níbi gbogbo,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 46

Wo Jeremáyà 46:5 ni o tọ