Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 46:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa Éjíbítì,Èyí ni ọ̀rọ̀ nípa àwọn ọmọ ogun Fáráò Nékò Ọba Éjíbítì ẹni tí a borí rẹ̀ ní Káṣímísì, ní odò Ẹ́fúrétà láti ọwọ́ Nebukadinésárì Ọba Bábílónì ní ọdún kẹrin Jéhóáíkímù ọmọ Jòsáyà Ọba Júdà:

Ka pipe ipin Jeremáyà 46

Wo Jeremáyà 46:2 ni o tọ