Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 44:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé ẹ̀yin ti gbàgbé ibi tí àwọn bàbá ńlá yín àti àwọn Ọba; àwọn ayaba Júdà, àti àwọn ibi tí ẹ ti ṣe àti àwọn ìyàwó yín ní ilẹ̀ Júdà àti ní òpópó Jérúsálẹ́mù?

Ka pipe ipin Jeremáyà 44

Wo Jeremáyà 44:9 ni o tọ