Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 44:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ìdí èyí, ìbínú gbígbóná mi ni èmi yóò yọ sí àwọn ìlú Júdà àti òpópó Jérúsálẹ́mù àti sísọ wọ́n di ìparun bí ó ṣe wà lónìí yìí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 44

Wo Jeremáyà 44:6 ni o tọ