Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 44:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Èyí ni yóò jẹ́ àmì fún un yín pé èmi yóò fi ìyà jẹ yín níbi tí Olúwa ti sọ láti lè jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé ìjìyà mi tí mo sọ pé ẹ̀ ó jẹ yóò ṣẹ.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 44

Wo Jeremáyà 44:29 ni o tọ