Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 44:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣe Ọlọ́run kò rántí ẹbọ sísun ní ìlú Júdà àti àwọn ìgboro Jérúsálẹ́mù láti ọ̀dọ̀ rẹ àti ọ̀dọ̀ àwọn bàbá rẹ, àwọn Ọba àti àwọn aláṣẹ àti àwọn ènìyàn ìlú.

Ka pipe ipin Jeremáyà 44

Wo Jeremáyà 44:21 ni o tọ