Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 43:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n tún kó àwọn ọkùnrin, àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé, àti àwọn ọmọ Ọba tí ó jẹ́ obìnrin èyí tí Nebusàrádánì tí ó jẹ́ adarí ogun ọ̀wọ́ tí ó jẹ́ olùsọ́ ti fi sílẹ̀ pẹ̀lú Jedaháyà ọmọ Élíkámù, ọmọ Sáfánì, àti Jeremáyà wòlíì náà àti Bárúkù ọmọ Néríà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 43

Wo Jeremáyà 43:6 ni o tọ