Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 43:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ásáríyà ọmọ Hòsáyà àti Jóhánánì ọmọ Káréà, àti gbogbo àwọn agbéraga ọkùnrin sọ fún Jeremáyà pé, “Irọ́ ló ń pa! Olúwa Ọlọ́run wa kò rán ọ láti sọ pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ lọ sí Éjíbítì láti tẹ̀dó síbẹ̀.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 43

Wo Jeremáyà 43:2 ni o tọ