Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 43:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò dá, iná sun Tẹ́ḿpìlì àwọn òrìṣà Éjíbítì, yóò sun Tẹ́ḿpìlì àwọn òrìṣà Éjíbítì, yóò sì mú wọn lọ ìgbèkùn. Gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́ àgùntàn, yóò ró aṣọ rẹ̀ mọ́ra, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni yóò ró Éjíbítì òun yóò sì lọ kúrò níbẹ̀ ní àlàáfíà

Ka pipe ipin Jeremáyà 43

Wo Jeremáyà 43:12 ni o tọ