Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 43:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí Ọlọ́run alágbára, Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: Èmi yóò ránsẹ́ sí ìránṣẹ́ mi Nebukadinésárì Ọba Bábílónì Èmi yóò gbé ìjọba rẹ̀ ka orí àwọn òkúta; èyí tí mo ti rì sí ibí yìí, yóò tan ìjọba rẹ̀ jù wọ́n lọ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 43

Wo Jeremáyà 43:10 ni o tọ