Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 42:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbá à ṣe rere, ìbá à ṣe búburú, àwa yóò gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run wa; èyí tí àwa ń rán ọ sí; Kí ó ba à lè dára fún wa. Nítorí pé àwa yóò gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run wa.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 42

Wo Jeremáyà 42:6 ni o tọ