Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 42:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì Jeremáyà sì dáhùn wí pé, “Mo ti gbọ́. Èmi yóò gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run yín gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin ṣe bèèrè. Èmi yóò sọ gbogbo ohun tí Olúwa bá sọ fún un yín, ń kò sì ní fi ohunkóhun pamọ́ fún un yín.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 42

Wo Jeremáyà 42:4 ni o tọ