Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 42:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa ẹ̀yin ìyókù Júdà èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì wí: ‘Bí ẹ̀yin bá pinnu láti lọ sí Éjíbítì láti lọ ṣe àtìpó ńibẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 42

Wo Jeremáyà 42:15 ni o tọ