Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 40:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jedáláyà ọmọkùnrin Áhíkámù, ọmọkùnrin ti Sáfánì ṣe ìbúra láti tún fi dá àwọn ènìyàn lójú pé, “Ẹ má ṣe bẹ̀rù láti sin àwọn Bábílónì.” Ó sọ wí pé, “Gbé ilẹ̀ náà kí ẹ sì máa sin Ọba Bábílónì, yóò sì dára fún un yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 40

Wo Jeremáyà 40:9 ni o tọ