Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kìnnìún ti sá jáde láti inú ibùgbé rẹ̀,apanirun orílẹ̀ èdè sì ti jáde.Ó ti fi àyè rẹ̀ sílẹ̀láti ba ilẹ̀ rẹ̀ jẹ́.Ìlú rẹ yóò di ahoroláìsí olùgbé.

Ka pipe ipin Jeremáyà 4

Wo Jeremáyà 4:7 ni o tọ