Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kọ ara rẹ ní ilà sí Olúwakọ ọkàn rẹ ní ilàẹ̀yin ènìyàn Júdà àti gbogbo ènìyàn Jérúsálẹ́mù,bí bẹ́ẹ̀ kọ́, ìbínú mi yóò ru jáde yóò sì jó bí iná,nítorí ibi tí o ti ṣekì yóò sí ẹni tí yóò pa á.

Ka pipe ipin Jeremáyà 4

Wo Jeremáyà 4:4 ni o tọ