Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 39:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn ọmọ ogun Bábílónì lé wọn, wọ́n bá Sedekáyà láàrin ihà Jẹ́ríkò. Wọ́n mú un ní ìgbékùn, wọ́n sì mú u tọ Nebukadinésárì Ọba Bábílónì àti Rábílà ní ilẹ̀ Hámátì, níbi tí wọ́n ti ṣe ìdájọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 39

Wo Jeremáyà 39:5 ni o tọ