Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 39:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò gbà ọ́ là; o kò ní ṣubú láti ipa idà; ṣùgbọ́n ìwọ yóò sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ, nítorí pé ìwọ ní ìgbàgbọ́ nínú mi, ni Olúwa wí.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 39

Wo Jeremáyà 39:18 ni o tọ