Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 39:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ sọ fún Ebedimélékì ará Kúṣì, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: Èmi ṣetan láti mú ọ̀rọ̀ mi ṣẹ lórí ìlú yìí nípa àjálù kì í ṣe àlàáfíà. Ní àkókò náà ni yóò ṣẹ lójú rẹ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 39

Wo Jeremáyà 39:16 ni o tọ