Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 38:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa mi Ọba, àwọn ènìyàn wọ̀nyí ti ṣe ohun búburú sí Jeremáyà òjíṣẹ́ Ọlọ́run. Wọ́n ti gbé e sọ sínú àmù níbi tí kò sí oúnjẹ kankan nínú ìlú mọ́.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 38

Wo Jeremáyà 38:9 ni o tọ