Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 38:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn olóyè sì wá sí ọ̀dọ̀ Jeremáyà láti bi í léèrè, ó sì sọ gbogbo ohun tí Ọba ní kí ó sọ. Wọn kò sì sọ ohunkóhun mọ́, nítorí kò sí ẹni tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ tí òun àti Ọba jọ sọ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 38

Wo Jeremáyà 38:27 ni o tọ