Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 38:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí ni ohun tí Olúwa wí: ‘Ẹnikẹ́ni tó bá dúró nínú ìlú yìí yóò kú nípa idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀-àrùn; ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tó bá lọ sí Bábílónì yóò yè; yóò sá àsálà, yóò sì yè.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 38

Wo Jeremáyà 38:2 ni o tọ