Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 38:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jeremáyà sì sọ fún Sedekáyà pé, “Tí mo bá fún ọ ní èsì, ṣé o kò ní pa mí? Tí mo bá gbà ọ́ nímọ̀ràn, o kò ní gbọ́ tèmi.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 38

Wo Jeremáyà 38:15 ni o tọ